Hymn 703
Beni Oluwa, iwo mo pe, mo feran Re.
Meter: C.M.
Scripture: Jn. 21:15
1
mfOlugbala mi, ife Re
Ha tobi be si mi?
Wo, mo fife mi, okan mi,
At’aya mi fun O.
2
Mo fe O nitori ’toye
Ti mo ri ninu Re,
pMo fe O nitori iya
T’o kun fun iyonu.
3
fBi iwo ti je Olorun
T’a f’ogo de lade;
diIwo ko ko awo eeyan
O f’ara da iya.
4
p’Wo je k’abi O l’eniyan,
Sugbon ’Wo ko l’ese;
crK’a wa le ri b’lwo ti ri,
K’a le se b’O ti se.
5
fK’a dabi Re ninu ife;
L’ewa ore-ofe;
crB’a ti nwoju Re, k’ama lo
L’at’ ogo de ogo.