Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 707

Oluwa ni Oluso-agutan mi, emi ki yio se alaini.

Meter: C.M.

Scripture: OD. 23: 1

1

fJesu l’Oluso-aguntan mi

Emi ki o salaini;

Nib’ odo at’oko tutu

L’o nfowo Re to mi.

2

fO mu k’okan mi tun soji,

O nto isise mi:

Ni ipa ona ododo,

N’tori oruko Re

3

pBi mo nrin nin’ojiji’ku

mfEmi ki o beru;

WO mbe pelu mi, opa Re

Y’o ma tu mi n’ inu.

4

mfIWO te tabili fun mi

Loj’ awon ota mi;

IWO d’ororo sori mi;

Ago mi kun, o nse

5

fIre at’ anu Re nto mi

Ni gbogbo aye mi;

Un o si fi ile Olorun

Se’bugbe mi laelae.