Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 708

Nitori Emi Oluwa Olorun re yo di owo otun re mu.

Meter: D.L.M.

Scripture: Isa. 41:13

1

fO nto mi lo ero ’bukun,

Oro t’orun tu mi ninu,

Ohun ti o wu k’emi je

Sibe Olorun nto mi lo

CHORUS

ffO nto mi lo, O nto mi lo

Owo Re l’o fi n to mi lo

L’otito ni mo fe te l'E

Nitoriti O nto mi lo

2

mpNigba miran t’iponju wa

Nigba miran l’ogba Eden’

L’eba odo, l’okun ’poju

fSibe. Olorun nto mo lo.

3

fOluwa mo d’owo Re mu

Nko ni kun, nko ni banuje,

F’ohun y’o wu ti mo le ri

Niwon t’Olorun mi nto mi.

4

Nigba’se mi l’aye ba pin

T’or’-ofe fun mi ni ’segun

Emi ko ni beru iku

Niwon t’Olorun mi nto mi.