Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 715

E ma a ru eru omonikeji yin.

Meter: C.M.

Scripture: Gal. 6:2

1

mf’Wo orisun ohun rere,

Awa fe se ’fe Re,

Ohun wo l’a le fi fun O,

Oba gbogbo aye?

2

L’aye yi, ’Wo ni otosi

crT’o je eniyan Re;

Oruko wo n’lwo njewo,

Niwaju Baba Re.

3

mp’Gba won ba nke n’inira won

Ohun Re l’awa ngbo;

Ki O pese fun aini won,

K’O da won l’ara ya.

4

Lara awon otosi Re,

L’oju ife Re wa;

’Gba ba si nse itoju won,

A nse si O, Baba.