Hymn 716
Nigbagbogbo li enyin sa ni talaka pelu yin.
Meter: 10.10.
Scripture: Mk. 14:7
1
mfMo nlo, talaka Mi mbe l’odo yin,
E le ma s’ore fun won b’e ti nfe,
2
mfEyi ni ogun t’Olugbala wa
Fi sile f’awon Tire k’o to lo.
3
Wura on jufu ko, otosi ni;
K’a ma ran won l’owo nitori Re.
4
crEru nla ko, ogun t’o l’oro ni;
Ti n f’ilopo ’bukun feni ntore.
5
mpTiwa ki ’se na bi? L’ojude wa
KO ni talaka at’ asagbe wa?
6
Ohun irora awon t’iya nje
Ko ha nke si wa lati f’anu han?
7
Okan t’o gb’ogbe, okan ti n sise
Ekun opo, at’alaini baba.
8
crOn t’O fara Re fun wa, si ti fi
Etu orun f’awa iranse Re.
9
Ko s’otosi kan ti ko le sajo
F’eni tosi ju lo, agbara ni.
10
Isin mimo ailabawon l’eyi,
Ti Baba mbere lowo gbogbo wa.