Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 717

On le pa ohun ti mo fe le lowo mo.

Meter: 11.11.11.11.

Scripture: II Tim. 1:12

1

mfJesu, emi o fi okan mi fun O

mpMo jebi mo gbe, Sugbon ’Wo le gba mi

crL’aye ati l’orun ko s’eni bi Re,

pIWO ku felese, f’emi na pelu.

2

mfJesu, mo le simi le oruko Re.

Ti angeli wa so, lojo Ibi Re,

pEyi t’a ko t’o han lor’ agbelebu,

crTi elese si ka, won si teriba.

3

mfJesu, emi ko le sai gbekele O,

Ise Re l’aye kun fanu at’ife,

mpElese yi O ka, adete ri O,

Ko s’eni buruju, ti ’Wo ko le gba.

4

mfJesu, mo le gbeke mi le oro Re,

Bi nko tile gbo ohun anu Re ri,

’Gbat’ Emi Re nko ni, o ti dun po to,

diKi nsa fi' barale k’eko lese Re

5

fJesu toto-toto mo gbeke le O,

Enikeni t’o wa, ’WO ki o ta nu,

ffOto ni ’leri Re, Owon l’eje Re

Wonyi ni gbala mi, ’WO l’Olorun mi.