Hymn 729
Sugbon, awon ti o ba duro, de Oluwa yio tun agbara won se.
Meter: 9.6.9.6. Ref.
Scripture: Isa. 40:31
1
mfEyin olukore nin'oko
T’are fere mu tan
crE roju duro de Oluwa,
Y'o s’agbara d'otun.
CHORUS
Awon t’o duro d’Oluwa,
Y’o s’agbara won d’otun,
fWon o fi iye fo,
Won o fi iye fo bi idi,
Won o sa, won ki y’o kare
Won o rin, ki y’o re won
Won o sa, won ki y’o kare
Won o rin, ki y’o re won
Won o sa, won ki y’o kare
Y’o rin, k’y’o re won.
2
pNigba are ati ’rewesi,
A ngb’okan wa si O;
mfLeyin t’a gba Olugbala gbo,
Ki l’ao tun beru.
3
fE yo! O mba wa gbe l’ojojo
Ani titi d’opin;
Woke! esi ma tesiwaju.
Y’o fun nyin l’agbara.