Hymn 738
Awa o duro sinsin ninu iranse na. .
Meter: 12.12.12. & Ref.
Scripture: Ise A. 6:4
1
fA o sise! Ao jise! Om’olorun ni wa,
Je k’a tele ipa ti Oluwa wa to;
mpK’a fi 'moran Re SO agbara wa dotun,
crK’a li gbogbo okun wa sise t’a ose.
CHORUS
fForiti! Foriti!
Ma reti: ma sona,
Titi Oluwa o fi de.
2
mfA o ise! Ao sise! bo awon t’ebi npa,
Ko awon alare lo s’orisun iye;
Ninu agbelebu l’awa o ma sogo,
’Gbati a ba nkede pe: “Ofe n’igbala’’
3
fA o sise! ao sise gbogbo wa ni y’o se,
Ijoba okunkun at’isina y’o fo;
A o si gbe oruko Jehofa l’eke,
N’nu orin iyin wa pe; “Ofe n’igbala’’
4
fA o sise! ao sise! lagbara Oluwa,
Agbada at’ ade y’o si je ere wa;
’Gbat’ ile awon oloto badi tiwa,
ffGbogbo wa ojo ho pe: “Ofe n’igbala.