Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 739

LO sise loni ninu ogba ajara mi.

Meter: 4.10.10.10.4.

Scripture: Mat. 21:28

1

Wa, ma sise,

fTani gbodo s’ole ninu oko

’Gbati gbogbo eniyan nkore jo,

Kaluku ni Baba pe fun ise;

“Sise loni.”

2

Wa, ma sise,

Gba ’pe giga ti angeli ko ni

Mu ’hinrere to t’agba t’ewe lo,

diRa ’gba pada, wawa l’akoko nlo,

Ile su tan.

3

mfWa, ma sise,

Oko po, alagbase ko si to,

crAye titun po fun wa lati kun,

Ohun ona jinjin, at’itosi

Nkigbe pe; “ Wa”

4

fWa, ma sise

Le ’yemeji on aigbagbo jina,

K’o s’alailera ti ko le se nkan,

diAilera f’Olorun a ma lo ju '

Fun’se nla Re

5

crWa, ma sise,

’Simi ko si nigbat’ ise osan,

Titi orun yio fi WO l’ale,

fTi awa o si gbo ohun ni pe:

“O seun, omo”

6

Wa, ma sise,

Lala na dun ere re si daju,

cr’Bukun f’awon t’o fori ti d’opin

Ayo won, ’simi won y’o ti po to!

p“Lo d’ Oluwa”.