Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 743

Ni ise sise e ma se ole.

Meter: 8.8.8.D.

Scripture: Rom. 12:11

1

mfAwon ti nfise won f’ale,

Won nfi t’Oluwa jafara;

Awon ti nfisin se ’boju

Ko mo ise on igbagbo;

Won ya’hun t’Olorun so PO

Aapon ati ifokansin.

2

mfA f’idi ise wa mule,

T’a nse pelu ’tara emi;

Olorun to da gbogb’ ojo,

Ni k’a simi l’OJO keje;

Ba ti nfise ra ’gba pada

Dun mo Oluwa ti a nsin.

3

A o ma yo, bi Olorun

Fun wa n’ise on itara;

crN’tor’ ise ti on f’ase si

fY’o di ebo fun ogo Re,

B’awon eni mimo l’oke

B’a ti njosin n’ife npo si.