Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 744

Baba mi nsise titi di isisiyi, emi si nsise

Meter: 8.6.8.6.8.6.

Scripture: Jn. 5:17

1

mpJesu ma yo mi n’nu’se Re.

TO mi fun ife Re;

N’tor’ emi ko le sa iri se

L’oko tito bi yi;

Emi ko ni bere oya

Ki nsa ma sin O si.

2

mfOpo li awon ti nsin O,

Aye wa f’opo si;

Ise itoju ajara

L’O yan f’awon miran;

Awon akoni mbe l’ogun

Omode mbe n’ile.

3

Gbogbo ise li o dara,

B’o ba sa ti wu O;

Bi osise nfife josin,

Ise re y’o wu O;

’WO ki o sai bukun ise

At’osise pelu

4

Jesu ti se iru ise;

T’On ni k’a se loni,

Eni ba ni’pin n’nu'se Re;

Y’o ba jogun pelu;

Un o sise ki nle j’omo Re;

diJowo mase yo mi.