Hymn 75
Emi mi si yo si Oorun Olugbala mi.
Meter: C.M
Scripture: Lk. 1:47
1
fEmi ‘ba n’egberun ahon,
Fun ‘yin Olugbala,
Ogo Olorun Oba mi,
Isegun ore Re.
2
pJesu t’o seru wa d’ayo
T’o mu banuje tan
Orin ni l’eti elese
Criey at’ilera
3
mfO segun agbara ese
O da onde sile,
DiEje Re le w’eleri mo,
PEje Re seun fun mi
4
crO soro, oku gb’ohun Re,
O gba emi titun,
Onirobinuje y’ayo,
Otosi si gbagbo
5
fOdi, e korin iyin re,
Aditi, gbohun Re;
Afoju, Olugbala de,
Ayaro, fo f’ayo
6
Baba mi at’Olorun mi,
Fun mi ni ‘ranwo Re;
FfKi nle ro ka gbogbo aye,
Ola oruko Re.