Hymn 755
Emi wa ki won le ni iye, ani ki won le ni lopolopo.
Meter: 11.11.11.11. & Ref.
Scripture: Jn. 10:10
1
crO ha ngbekele Jesu n’gbogb’ona re?
O ha nd’otun lokan re lojojumo?
O ha j’om’eyin Re? ye oro Re wo.
Y’o fun o l’Emi Mimo lopolopo
CHORUS
mfLopolopo si, lopolopo si,
Ki won le ni iye si lopolopo
Lopolopo si, lopolopo si,
Ki won le ni iye si lopolopo,
2
mfFun oju rere Re, gbe oko Re ga,
Olugbala wa to t’orun sokale,
K’awon ayanfe Re juba oro Re.
Eni ra wa pada nipa eje Re
3
crWa pelu igbagbo, wa je ipe Re
Eyin t’a mbukun, jowo ara yin fun;
Jesu, y’o gb’eni t’o sa wa sodo Re,
Y’O da ’bukun Re lu o lopolopo.