Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 758

A fi ipile re sole lori apata.

Meter: 14.9.14.9. & Ref.

Scripture: Mat. 7:25

1

mfA n kole l’or’apata t’ijikiji ko le mi,

’Pile wa daju, o lagbara;

Ise wa nihin ni lati segun gbogbo ibi,

K’a si gbekel’Orisun ’ranwo

CHORUS

crApata

(A nkole l’or’Apata,)

Apata,

(L’or’Apata to daju,)

Apata ayeraye to duro lae (duro lae)

Apata

(A nkole l’or’ Apata,)

Apata

(Apata to ni ’bukun)

fA nkole l’or’Apata, Kristi Jesu.

2

crKo si ’pile ta le fi sole lon’aiinokan wa

To le duro b’igbi ’ponju do;

fSugbon lori Krist’ Apata l’abo to daraju,

Nitori ike Re l’o daju.

3

mfJe ka sise, ka ko’rin ninu tempil'mimo yi.

Ninu ’sin Re ao ri ’bukun gba;

Taba f’ayo ati ’sowopo sise f’Oluwa

Ere wa ni ayo ailopin