Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 759

Omo, lo loni ninu ogba ajara mi.

Meter: 7.7.7.7.D

Scripture: Mat. 21:28

1

mfGbo b’Olugbala ti wi

Pe ise po n'nu ogba;

Alagbase ko si to

crO mura ‘se na bi

Afunrugbin funrugbin,

Oko pon, ikore de,

Olukore mu doje

Lati ko 'rugbin wale.

2

fOlugbala nke tantan

P’eyin onise dide,

Gbe Ihamora mi wo,

Mura fun 'se lat’ oni

Akoko mure tete,

Ojo Ikoro de tan,

Olukore ti se tan,

Lati ko iti wole.

3

mfWundia mewa la yan,

diMarun ko mura sile;

Marun to ti mura tan

Ba Oba Ogo wole.

crLo talent ta fi fun o,

Sse ’ranse re loni

Fori ti, tesiwaju,

'Wo o gbade isegun.

4

fGbo ipe Olugbala,

Wa je ’pe na nisiyi,

Mase f’akoko dola,

Ojo igbala de tan.

crOhun to npe nisiyi

Le dekun ipe lola,

Se ’pinnu rere loni

Ko le gba ade ogo.

5

mfOluwa, Olorun mi,

Un O fi ayo jise Re;

crFun mi ni ebun ahon,

Ki njise na laiberu;

Nigbayi li okan mi

Y’o ma korin iyin pe:

fTi Oluwa Olorun

Ni iyin ati ogo.