Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 76

Oluwa, Olorun mi, Iwo tobi jojo.

Meter: 610.10.11.11

Scripture: OD. 104:1

1

fE wole f’Oba, Ologo, julo,

E korin ipa ati ife Re;

Alabo wa ni at’Eni igbani,

O ngbe ‘nu ogo, Eleru ni iyin

2

E so t’ipa Re, e so t’ore Re;

‘Mole l’aso Re, gobi Re orun,

CrAra ti nsan ni keke ‘binu Re je,

Ipa ona Re ni a ko si le mo

3

mAye yi pelu ekun ‘yanu Re

Olorun agbara Re l’o da won,

O fi idi re mule, ko si le yi;

O si f’okun se aso igunwa Re

4

crEnu ha le so ti itoju Re?

Ninu afefe ninu imole;

DiItoju Re wa nin’odo ti o nsan

PO si wa ninu iri ati ojo

5

mpAwa erupe aw’alailera

‘Wo l’a gbekele, O ki o da ni

CrAnu Re rorun o si le de opin

FEleda, Alabo, Olugbala wa

6

ff‘Wo Alagbara Onife jule

B’awon Angeli ti nyin O loke

DiBe ‘awa eda Re, niwon t’a le se

CrA o ma juba Re, a o ma yin O