Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 77

Oun li Oluwa awon luwa ati Oba awon oba.

Meter: C.M

Scripture: Ifi. 17:14

1

fGbogbo aye, gbe Jesu ga,

DiAngel’, e wole fun;

CrE mu ade Oba Re wa,

FSe l’Oba awon Oba

2

mfE se l’Oba ein Martyr,

Ti npe ni pepe Re;

CrGbe gbongbo igi, Jese ga

FSe L’Oba awon oba

3

mfEyin iru omo Israeli’,

Ti a ti rapada;

CrE ki Eni t’o gba yin la,

FSe l’Oba awon oba.

4

pGbogbo eniyan elese

Ranti ‘banuje yin;

CrE ti ‘kogun yin s’ese Re,

FSe l’Oba awon oba

5

ffKi gbogbo orile ede,

Ni gbogbo agbaye,

Ki won ki, ‘”kabiyesile”

Se l’Oba awon oba

6

mfA ba le pel’awon t’orun

Lati ma juba Re;

CrK’a bale jo jumo korin,

FfSe l’Oba awon oba