Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 772

Enikeni ti a ti pa Olorun bi ki i dese

Meter: S.M.

Scripture: I Jn. 3:9

1

mfKi nma batun d’ese

Ti Olorun mi ko;

Oluwa, se atunda mi '

Si s’okan mi d’otun.

2

Nigbana l’okan mi

Yo korira egbin;

B’lfe Re ti ya si mimo

Ki o si d’ese mo.

3

Ofin Re mimo ni,

Jesu jo li ko mi;

crOfin Emi nipa iye

Jo ko si aye mi.

4

Gbin sinsin sinu mi,

Ko ma le sipo lae;

Ofin ’dande kuro n’n’ ese

Ofin pipe t’ife.

5

mfK’iwa Re je temi,

Iwa ailaba won;

Mo fa okan mi s’odo Re.

Ni wakati gbogbo.

6

f’WO ni ’ye emi mi,

Oludande aye;

Mu ife Baba Re orun

Se ninu aye mi.