Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 778

Bi enikeni ba nsin mi ki o ma to mi lehin.

Meter: 7.6.7.6.D.

Scripture: Jn. 12:26

1

mpJesu, mo ti se ’leri

Lati sin O d’opin;

Ma wa l’odo mi titi,

Baba mi, Ore mi;

Emi k’y’o beru ogun

B’IWO ba sunmo mi,

Emi ki yo si sina

B’O ba f’ona han mi.

2

Je ki nmo p’O sunmo mi

Tori ’baje aye;

Aye fegba okan mi,

Aye fe tan mi je;

diOta yi mi kakiri,

L’ode ati ninu;

crSugbon Jesu sunmo mi,

Dabobo okan mi.

3

pJeki nma gbo ohun Re,

B’O ti mba mi soro,

Larin iji idanwo,

ASO at’agidi;

crSO, mu ko da mi loju,

K’okan mi ni ’janu;

SO, si mu mi gbo Tire,

’WO Olutoju mi.

4

mfJesu,’WO ti se’leri

F’awon t’o tele O,

Pe ibikibi t’O wa

N’iranse Re yo wa;

Jesu, mo ti se ’leri

Lati sin O dopin,

Je ki nle to O leyin,

Baba mi, Ore mi.

5

pJeki nma ri ’pase Re

Ki nle ma tele O;

Nipa ’gbara Re nikan,

Ni mo le tele O:

To mi, pe mi, si fa mi,

Di mi mu de opin;

Si gba mi si odo Re,

Baba mi, Ore mi.