Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 78

Mo gbohun nla kan ti opolopo eniyan Lorun, wipe Aleluya.

Meter: 8.7.8.7.8.7

Scripture: Ifi 19:1

1

fAleluya! Orin t’o dun,

Ohun ayo ti ki ku;

Aleluya! Orin didun,

A’won t’o wa lorun fe;

N’ile ti Olorun mi ngbe

Ni won nko tosantoru

2

Aleluya! Ijo t’orun,

E le korin ayo na

Aleluya! Orin ‘Segun

Ye awon ta rapada

Awa ero at’aljo

DiIyin wa ko nilari

3

mpAleluya! Orin ayo

Ko ye wa nigba gbogbo

Aleluya! Ohun aro,

Da mo orin ayo wa;

PGba t’awa laye osi yi

DiA ni gbawe f’ese wa

4

crIyin dapo m’adura wa

Gbo tiwa, metalokan!

Mu wa de ‘waju Re layo

K’ar’Od’aguntan t’apa

FK’a le ma ko Aleluya

Nibe lae ati laelae