Hymn 786
KO mi li Ona Re, Oluwa.
Meter: 6.6.6.6.
Scripture: OD. 27:11
1
crOna Re, Oluwa,
B’o ti wu ko ha to!
Fi owo Re to mi;
Yan ipa mi fun mi.
2
B’o rorun, b’o soro,
Dara dara lo je;
B’o wo, b’o to tara,
Lodo Re l’opin si.
3
crNko gbodo yan ’pin mi;
Nko tile je yan an;
Yan fun mi Olorun:
Ki mba le rin dede.
4
Ijoba ti mo nwa,
Tire ni; jek’ona
T’o re ’be je Tire,
Bi beko un o sina.
5
mpGba ago mi, fayo
Tab’ibanuje kun
B’o ti to l’oju Re;
pYan ’re tab’ ibi mi.
6
diYiyan ki se temi
Ninu ohunkohun;
mfIwo s’Oluto mi,
Ogbon, ohun gbogbo.