Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 788

Won sijoko li ese re; olukuluku yio gba ninu oro re.

Meter: C.M.

Scripture: Deut. 33:3

1

mfEnit’eje Jesu we mo

Ko ni fi ese se;

A pa wa mo l’owo Jesu

A si nrerin ewu.

2

L’oniruru ona ’yanu

L’OWO Re ndabobo

Awon mimo, t’o gbekele

Igbala Re nikan.

3

crWoli, Alufa, Oba wa,

A f ayo juba Re,

A si nfirele gba eko

Li abe ese Re.

4

mfOro Re nfi iye fun ni,

At’ibukun orun,

crJeki mana ife Re bo

Sinu okan gbogbo.