Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 79

Fi ibukun fun Oluwa, Iwo okan mi.

Meter: 8.7.8.7.4.7

Scripture: OD. 103:1

1

fOkan mi yin Oba orun,

Mu Ore wa sode Re,

mp‘Wo ta wosan, t’a dariji

crTal’aba ha yin bi Re?

Yin Oluwa, Yin Oluwa

fYin Oba Ainipekun

2

mfYin fun anu t’o fi han

F’awon Baba ‘nu ponju;

Yin l’Okan na ni titi

O lora lati binu

fYin Oluwa, Yin Oluwa,

Ologo n’nu otito

3

pBi Baba ni O ntoju wa

O si mo ailera wa;

Jeje l’o ngbe wa lapa Re

O gba wa lowo ota,

Yin Oluwa, Yin Oluwa

Anu Re, yi aye ka

4

ffAngel, e jumo ba wa bo

Eyin nri lojukoju

Orun, Osupa, e wole

Ati gbogbo agbaye

E ba wa yin, E ba wa yin

Olorun Olotito.