Hymn 791
Efi ayo sin Oluwa.
Meter: 7.6.7.6. & Ref.
Scripture: OD. 100:2
1
fJ e oloto s’Oluwa
T’O femi Re fun o;
'Ninu ewu at’ibi,
Je akoni toto.
CHORUS
mfJ’oloto si Jesu,
Gb’asia Re soke n’bi gbogbo
J’oloto si Jesu;
Je akoni lati sise;
crNigba t’ija ba sile
Gbekele Olorun Re;
Sise rere;
mfKorin ’yin Re;
J’oloto s’Oba re.
2
J’oloto nibikibi,
L’ojo tabi l’erun,
Lo sibi to nto O si;
N’igbadun, n’irora.
3
mpMase sise imele.
mfDuro gbonin n’ipa Re
Mu oro na yara de
Tao ni ’segun pipe.
4
fJ’oloto bi agbara
Okunkun yi o ka;
Angel Re y’o ma so o,
Ipa Re l’orin re.