Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 80

Emi o so ti iseun ife Oluwa.

Meter: L.M

Scripture: Isa. 63:7

1

fJi, Okan mi, dide l’ayo,

Korin iyin Olugbala,

Ola Re bere orin mi;

p‘Seun ife Re ti po to!

2

mfO ri, mo segbe n’isubu,

Sibe O fe mi l’a fe tan

O yo mi ninu osi mi;

p‘Seun ‘fe Re ti tobi to!

3

mfOgun ota dide simi,

Aye at’esu ndena mi,

On mu mila gbogbo Re ja

‘Sun ‘fe Re ti n’ipa to!

4

f‘gba ‘yonu de b’awosanma

T’o su dudu t’o nsan ara

O duro ti mi larin re;

‘Seun ‘fe Re ti dara to!

5

‘Gba gbogbo l’okan ese mi,

Nfe ya l’eyin Oluwa mi

Sugbon bi mo ti ngbagbe Re

Iseun Ife Re ki ye