Hymn 802
Bi o se temi ati ile mi, Oluwa lawa o sin.
Meter: 8s. 6s.
Scripture: Jos. 24:15
mfEmi at’ ara ile mi,
Yoo ma sin Oluwa wa
crSugbon emi papa
Yoo fiwa at’oro han,
Pe mo mo Oluwa t’orun,
Mo nfokan toto sin.
mfEmi o f’apere ’re le le;
Un o mu idena na kuro
Lodo om’ odo mi
crUn o f’ise won han ni iwa mi
Sibe n’nu ’se mi ki nsi ni
Ola na ti ife.
Emi ki y’o soro gb’ipe
Emi y’o pe tu ninu
Om’eyin Olorun
crMo si fe je eni mimo
Ki nsi fa gbogbo ile mi
S’oju ona orun.
crJesu, b’o ba da ’na fe na
Ohun elo t’Iwo felo,
Gba s’owo ara Re
Sise ife rere n’nu mi
Ki nfi b’onigbagbo toto
Ti ngbe l’aye han won,
crFun mi l’or’ofe toto
Nje! Emi de lati jeri
’Yanu oruko Re
Ti o gba mi lowo egbe
Ire eyi t’a mo l’okan
Ti gbogb’ ahon le so
mfEmi t’o bo lowo ese,
Mo wa lati gba’le mi la
Ki nwasu ’dariji:
F’omo, faya f omo ’do mi
Lati mu won to’na rere
Lo si orun mimo.