Hymn 804
Sugbon ife ti emi ko, bikose Tire ni ki a fe.
Meter: 10.4.10.4.10.4.
Scripture: Lk. 22:42
1
mpOluwa, Olorun mi, se ’fe Re,
Nki o mi ra,
pNko ni dide, ki nma ba sesi ta
Owo na nu,
Ti nmu mi ro mo aya
Baba mi Ni isimi.
2
mfOkan ti nj’ ijakadi ni Kristi
Nfun l’agbara;
pIwaya ija Re oru ’gbati
Ko s’enikan,
Ju Baba, at’angeli rere kan
Ti nt’U ninu.
3
mp“Baba, ’fe mi ko, Tire ni k’ase
Be l’Omo wi,
crK’eyi j’asiri wa larin gbogbo
Lala aye,
pK’a le ro mo aya
Re titi lae Ni isimi.