Hymn 808
Eyi ha ise akoko atigba fadaka Ati lati gba ASO?
Meter: 13.13.13.13. & Ref.
Scripture: II A. Oba 5:26
1
mfOluwa nko bere fun fadaka on wura
Un o jijakadi f’orun un o si wo ’nu agbo
N’nu iwe ijoba Re ti o lewa pupo
So fun mi, Oluwa mi, ooko mi ha wa nbe
CHORUS
crOoko mi ha wa mbe
Ninu iwe nla ni
Iwe ti ijoba Re
Ooko mi ha wa mbe.
2
mpOluwa ese mi po bi iyanrin okun
Sugbon eje Re, Jesu, tito fun gbogbo re
’Tori ’Wo ti se ’leri ninu oro Re pe,
“B’ese re pon b’ododo, un o fo won fun bi aso.
3
fNi ’lu daradara ni, ibugbe imole,
Nibi t’awon mimo wa, nin’asp funfun won
T’ohun-eri ko le de lati b’ewa re je
N’bi t’awon Angeli nso, ooko mi ha wa mbe