Hymn 809
’Gbat’ab’Oluwarin N’nu ’mole oro Re
Meter: 6.6.9.6.6.9. & Ref.
Scripture: Mat. 11:29
1
mf’Gbat’ab’Oluwarin
N’nu ’mole oro Re;
Ona wa yio ti mole to!
’Gbat’a ba nse ’fe Re.
On y’o ma ba wa gbe,
Ati awon t’o gbeke won le.
CHORUS
fSagbekele,
Ona miran ko si
Lati l’ayo n’nu Jesu,
Ju pe, ka gbekele.
2
mfKo s’ohun to le de,
Loke tabi n’ile,
To le ko agbara Re l’oju;
crIyemeji, eru,
Ibanuje, ekun
mfKo le duro, bi a gbekele.
3
fKo si wahala mo,
Tabi ibanuje.
O ti san gbogbo ’gbese wonyi
Ko si aro kan mo,
Tabi ifajuro,
Sugbon ’bukun b’a ba gbekele.
4
A ko le fenu so
Bi ’fe Re ti po to
Titi ao fi fara wa rubo;
mfAnu ti On fihan
At’ayo t’O nfun ni
Je ti awon ti o gbekele.
5
Ni ’dapo pelu Re,
Ao joko l’ese Re.
Tabi ki a ma rin pelu Re,
Awa yo gbo Tire,
Ao jise t’Oran wa,
fMa beru, sa gbekele nikan.