Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 812

E tujuka, mo ti segun aye.

Meter: L.M.& Ref.

Scripture: Jn. 16:33

1

fIsegun wa li okan mi,

Nitori Emi ngbe ’nu mi;

Jeki igbi idanwo de,

Jesu mura lati gba mi.

CHORUS

ffIsegun! Isegun! ’segun l’okan mi,

Mo ni isegun nla ’tori Jesu gb’okan mi

Isegun! Isegun! bi odo sisan,

Mo ni ’segun nla ninu eje Jesu.

2

crBi ’ja tile le to si pe,

B’esu tile b’okan mi ja;

mfSibe, mo je alagbara,

fL’agbara Jesu, ngo segun.

3

fMo ni ’segun lori ese,

Mo ni ’segun lori ’boji,

Ani iku ko ni ’pa mo,

ffAleluya! emi ti la.