Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 814

Nitoto Oun o gba O LOWO ikekun awon peyepeye.

Meter: 11.12.11.10 & Ref.

Scripture: OD. 91:3

1

mfEru ’ji ko ba mi, won yoo dekun;

’Danwo ko le pa mi, ’tori mo l’alafia;

Gbogb’ohun ti mo ko sile, nko fe mo,

Un o r’ohun to ju won lo ni Kenan'

CHORUS

fAwon to fe le duro n’Egypt,

Emi nlo si Kenan’

Nibi wara at’oyin, yoo te wa l’orun;

Lehin ajasegun, ayo at’alafia je temi;

Okan mi yo simi l’ebute Re.

2

mfWahala ko ni pa, ko le duro pe;

Won le wa yi mi ka, un o sa s’odo Jesu;

Gbogb’aye le daru, ko si mi titi;

Ko si iji ni ebute Kenan’

3

mfN’nu opo ore-ofe, emi fe wa

Li abe ojiji ti Kenan’ ti o pe;

Gbogbo ’gbekele mi le ye, ko je nkan;

Ko s’ohun to le se mi ni Kenan’ .