Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 816

Aye si nkoja lo ati ifekufe re, sugbpn eniti o ba nse ife Olorun ni yio duro laelae.

Meter: 10.10.10.7. & Ref.

Scripture: I Jn. 2:17

1

mfB ’aye ba nfa mi pelu ogo re,

Ko s’ewu, omo Olorun ni mi,

fOwo agbara Re yo di mi mu,

L’ojo aye mi gbogbo.

CHORUS

Mo l’ore t’O npese f’aini gbogbo,

Mo n’ile kan loke orun giga,

Wo! Nitori idi eyi na ni,

fEmi se nko Aleluya!

2

crEmi ko je gbagbe pe lor’igi,

Ni Omo Olprun gbe ku fun mi;

Ko le saiku lati gb’okan mi la,

Ko tun si ona miran.

3

mfUn o j’oloto s’Oluwa Oba mi,

Uno ma korin ’yin si nigbagbogbo,

Mo mo pe nikehin; On yo gba mi;

Lati ma ba gbe titi.