Hymn 817
Oluwa ni mo gbeke mi le.
Meter: 8.7.8.7. & Ref.
Scripture: OD. 11:1
1
mfKi ngbekele Olugbala,
L’odo Re mo ni ’bukun,
crKi wahala to yi mi ka
Mu mi sunmo odo Re.
CHORUS
fGbekele lojojumo,
Gbekele Jesu titi;
Ohunkohun to le de,
Gbekele Jesu nikan.
2
mfNi’gbekele ojiji Re,
Nigbati orun ko si;
mpBo ti wu k’oju orun su,
mfIfe Re yo tan’mole
3
mfGbekele imole Re lae
Ko ’yemeji at’eru;
Lori oke pelu Jesu
Gbe okan re s’oke s’l.