Hymn 818
Sugbon emi kiyo gbagbe re.
Meter: 9.8.9.7. & Ref.
Scripture: Isa. 49:15
1
mpNigba ti ona mi ba sokun,
Ti ojo ibi ba si de;
crEmi nranti ileri yi pe:
mfOn ko je gbagbe Tire.
CHORUS
On ko je gbagbe Tire,
On ko je gbagbe Tire,
crBi ore sa, On wa nitosi,
fOn ko je gbagbe Tire.
2
mpNigbati ’reti gbogbo ba pin,
T’iyemeji at’eru de,
Un o wa ’simi l’aya Eni ti,
Ko le je gbagbe Tire.
3
fOn ko je gbagbe Tire laelae;
O se owon fun mi pupo,
Lati ’gbati O ti sokale.
Ti O ngbe ’nu okan mi.