Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 822

Nitori Emi li Oluwa, Emi koyipada.

Meter: 6.6.8.6.8.8.

Scripture: Mal. 3:6

1

mpNihin l’ayida wa;

Ojo, erun, nkoja,

diIle ni nyan ti o si nsa,

’Tanna dada si nre;

fSugbon oro Kristi duro:

“Un o wa pelu re” ni On wi.

2

mpNihin l’ayida wa,

L’ona ajo orun;

N’nu ’gbagbo ’reti at’eru,

N’nu ’fe s’Olorun wa:

diA nsalka oro yi si ’po!

“Un o wa pelu re”, ni Kristi wi.

3

mpNihin l’ayida wa;

crSugbon l’arin eyi:

L’arin ayidayid’aye,

fOkan wa ti ki yi;

ffOro Jehofa kii pada:

“Un o wa pelu re”, ni On wi.

4

mpOna alafia;

Imanueli wa,

ffMajemu ti ore-ofe,

Lae, won ki yi pada

cr“Nki yi pada,” l’oro Baba,

“Mo wa pelu re”, ni On wi.