Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 834

Ki a mase ri pe emi nsogo bikose ninu agbelebu Jesu Kristi Oluwa wa.

Meter: 7.7.7.7.D.

Scripture: Gal. 6:14

1

mpMo mbo nib’agbelebu,

Emi abosi julo;

Mo ka gbogbo nkan s’ofo

Lati ri ’gbala kikun.

CHORUS

crMo gbekele O, Jesu

Odagutan Kalfari,

diMo fi ’rele teriba,

Gba mi, Jesu, loni yi.

2

mfMo gbekele ’leri Re,

At’agbara eje ni,

mpMo pon ara mi l’oju,

Mo nru agbelebu Re.

3

mfJesu fi ayo kun mi,

O si so mi di pipe;

Mo ni ilera pipe;

fOgoni f’Od’agutan.