Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 837

Lati inu ibu wa li emi kepe O, Oluwa.

Meter: 7.7.7.5.

Scripture: OD. 130:1

1

‘Wo t’O ku ni Kalfari,

‘Wo t’O mbebe f’elese

crRan mi lowow nigb’aini;

Jesu, gbo ‘gbe mi

2

mpNinu ibanuje mi

At’okan aigbagbo mi

pEm’olori elese

Gb’oju mi si O

3

pOta l’ode, eru n’nu,

Ko s’ire kan lowo mi;

Iwo l’O ngb’elese la,

crMo sa to O wa

4

Awon iran d’ese pe,

Won si ir igbala gba;

crWon gbo ohun anu Re,

Mu mi gbo pelu

5

mpMo k’aniyan mi le O,

Mo si ngbadura si O,

Jesu yo mi n’nu egbe;

Gba mi ki nma ku.

6

cr‘Gbati wahala ba de,

Nigb’ agbara idanwo;

Ati lojo ikeyin

Jesu, sunmo mi.