Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 839

Mo ti gbadura fun o ki igbagbo re ma seye.

Meter: 6.5.6.5.D.

Scripture: Lk. 22:32

1

mpJesu nigba ’danwo

Gbadura fun mi;

K’emi ma ba se O

Ki nsi sako lo,

cr’Gba mba s’iyemeji

KO b’oju wo mi,

K’eru tab’ isaju

Ma mu mi subu.

2

mpB’aye ba si nfa mi

Pelu adun re,

T’ohun ’sura aye

Fe han mi l’emo,

Jo mu Getsemani

diWas’iranti mi,

ppTabi irora Re

L’oke Kalfari.

3

mpB’O ba pon mi l’oju

Ninu ife Re.

Da ibukun Re le

Ori ebo na;

Ki nf ara mi fun O

L’ori pepe Re:

B’ara ko ago na,

lgbagbo y’o mu.

4

p‘Gba mo ba nre ‘boji

Sinu ekuru;

crT’ogo orun si nko

l’eti bebe na;

mfUn o gbekel’ oto Re

Ni ‘jakadi ‘ku

Oluwa gb’emi mi,

S’iye ailopin