Hymn 849
Mo ti pe o li oruko re; ti emi ni iwo.
Meter: 8.8.8.D.
Scripture: Isa. 43:1
mfM ase beru ’wo okan mi;
Eleda mi ni nma foya;
Oluwa pe mi l’oruko;
O ndabobo, ko si jinna,
Eje Re ti s’etu fun mi,
O nfe, O si nto mi sibe.
cr’Gba mo nkoja larin ibu,
Mo fi gbagbo toro ’ranwo,
Igbi si duro l’okere,
Won bi kuro li ori mi:
mfEmi ko beru ipa won;
Ko si ewu, Olorun mbe.
Mo yio ju igbagbo s’I,
Mo n tesiwaju larin ’na;
Ina gbagbe lati jo mi,
Owo ina njo yi mi ka;
MO JEWO agbar'ami na,
Mo ke pe: “Temi m Jesu”.
crOlugbala, duro ti mi;
Dabobo mi nigba ’danwo
Pa mi mo ni ikawo Re,
F’agbara ’gbala han n’nu mi;
Ki apa Re je abo mi,
Ko s’ohun le ja mi kuro.
B’O si ti pe mi pe ki nwa ’
WO; Olore, ti ngba ni la,
Un o rin lori okun ti nja,
Igbi yo gbe ese mi ro;
Nki yo beru isan na,
Bi o ti wu ki o le to.
mp’Gbat’okunkun b’oju orun
T’igbi ’banuje yi mi ka,
T’iji ibinu ru soke,
To fere bori okan mi,
mfEmi mi yo ri ’dake-je,
ppYo gb’ohun jejepe, “simi!”
fBi mo wa n nu eru’ponju,
Laisewu un o sete iku;
B’ese doju ija ko mi,
Ti esu gbe ogun ji mi,
B’igbo Mose, un o magberu,
Ina ki o pa mi lara.