Hymn 854
Nitori ti Oun nse itoju n yin
Meter: 8.8.8.6. & Ref.
Scripture: I Pet. 5:7
1
mfN’nu gbogbo ’danwo ti mba mi
Larin idamu aye yi;
crIro kan lo nmu ’nu mi dun
mfBaba ngbero fun mi.
CHORUS
fBaba ngbero fun mi,
Baba ngbero fun mi,
Eese ti un o tun ma beru?
Gbat’O ngbero fun mi.
2
mp’Gbat’ igbi aniyan ba de
Lati teri okan mi ba;
crSibe mo ranti ohun kan
mfPe: ’Wo ngbero fun mi.
3
crOhunkohun to wu ko de;
Ayo tabi ibanuje,
Ohun kan sa da mi loju
mfPe: ’Wo ngbero fun mi.