Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 855

Beulah nitori inu Oluwa dun si O.

Meter: 14.14.14.10. A Ref.

Scripture: Isa. 62:4

1

mpMo n gburo iji ti nja li ona jinjin rere

Mo si mo pe ese ndan ni wo ni aye yi

mfIye meji at’eru ko le pami lara mo

Wonyi ko le mu mi kuna Beulah.

CHORUS

fMo ngbe ni ori oke, gbogbo ’danwo si fo lo (yin Krist’),

Mo nmu n’ibi orisun ti ko le gbe titi,

Mo nje onje na t’ise Manna lati oke orun waa

Nitori mo ngbe nile Beulah.

2

mfMo jinna s’ibiti iyemeji ndamu aye,

Nibiti ota ngbogun ti omo eniyan;

Mo ngbe lailewu li ebute oro Olorun,

Ko s’ewu ’tori mo ngbe ni Beulali.

3

mfBo ti wu ki iji le to, eru ko le ba mi,

OWO Olorun li abo to daju fun ini;

Nibe l’orun nran titi, ko si ifoya tun mi

Ko s’ewu ’tori mo ngbe ni Beulah.

4

p‘Gbati mo now ‘se Olorun okan mi wariri

crMo n gb'ohun ife Re pe On lo nseto fun mi,

Emi Re nfihan mi pe igbala didun l’eyi

mfUn o fi ayo gbe ni ile Beulah.