Hymn 86
Awon eni-irapada Oluwa yio pada, WON o si wa si Sioni ti awon ti orin; ikanu ati ofo yio fo LO.
Meter: 7.7.7.5.
Scripture: Isa. 51:11.
1
fOlorun Metalokan,
Oba ile at’okun,
Gbo ti wa bi a ti nko
Orin iyin Re.
2
f’Wo imole l’owuro
Tan ’mol? Re yi wa ka
Je ki ebun rere Re
pM’aya wa bale.
3
f’WO ’mole ni gb’orun WO
K’a ri idariji gba
Ki alafia Orun
pF’itura fun wa.
4
fOlorun Metalokan!
Isin wa l’aye ko to!
A nreti lati dapo
Mo awon t’orun