Hymn 861
Gbo, Oluwa, nigbati mo bafi ohun mi pe: sanu fun mi.
Meter: 1.1.1.5.
Scripture: OD. 27:7
1
crOlorun, Olor’-ofe,
’Gbat’a nfi ’rele wa o,
mpBojuwo ’le lat’orun;
’Gbo, si gbawala.
2
’Gba ba pejo n’ile Re,
T’a nso ohun t’o ndun wa,
T’a nbebe n’ite anu,
crWo wa, gba wa la
3
’Gba’fe Re kun okan wa
Ti a nfe Se ’feTire,
T’a nwo oke mimo Re,
crBaba, gba wa la.
4
mpB’a ba sako jinna lo,
pT’ife wa tutu si O,
crF’oju anu Re wo wa;
JO dariji wa.
5
mp’Gbati ’banuje ba de
Pelu idamu aye,
crF’alafia f’okan wa;
Jesu, gba wa la.
6
crOhun wu k’edun wa je,
’Gbat’ a ngbadura si O,
F’opin si ipaya wa;
Gbo, si gba wa la.