Hymn 862
Dide, Oluwa, Olorun gbe owo Re soke: mase gbagbe oluponju:
Meter: C.M.
Scripture: OD. 10:12
1
crOlorun, ’ranwo eni Re;
’Reti wa n’igba ’bi,
A gba ’WO Eni Airi gbo,
mpAwa nwa O sibe
2
crEse ti awon elese
Nfojudi ipa Re,
diTi won si nhale b’enipe
’WO ko ri ese won?
3
Oluwa, dide k’o gba wa;
A m’oran wa t’o wa,
F’ododo at’ipa j’oba,
’WO nikan li Oba.
4
mfIWO mo gbogbo ife wa;
’Ranwo Re wa n’tosi
Pese okan wa fadura,
Si gba adura wa;