Hymn 869
Eni ti o si gbekele Oluwa, ibukun nifun.
Meter: L.M. & Ref.
Scripture: Owe 16:20
1
fOjo nla l’ojo ti mo yan
Olugbala l’Olorun mi;
O ye ki okan mi ma yo,
K’o si ro ihin na kale
CHORUS
fOjo nla l’ojo na
pTi Jesu we ese mi nu;
O ko mi ki nma gbadura
Ki nma sora, ki nsi ma yo,
Ojo nla l’ojo na
Ti Jesu we ese mi nu.
2
mfIse igbala pari na,
Mo di t’Oluwa mi loni;
On l’o pe mi, ti mo si je,
ffMo f’ayo j’ipe mimo na.
3
Eje mimo yi ni mo je
F’eni to ye lati feran:
Je k’orin didun kun ‘le RE
Nigba mo ba nlo sin nibe
4
Simi, aiduro okan mi,
Simi le Jesu Oluwa;
Tani je wipe aye dun,
Ju odo awon angeli?
5
’Wp orun t o ngbo eje mi,
Y’o ma tun gbo lojojump,
pTit’ ojo t’emi mi y’o pin
Ni un o ma m’eje mi na se