Hymn 87
E fi iyin fun Oluwa.
Meter: 6.6.6.6.8.8.
Scripture: OD. 146:1.
1
mfA Fiyin ailopin
Fun Olorun Baba,
Fun ore aye wa
At’ireti t’orun,
O ran Qmo Re ayanfe
pLati ku fun ese aye.
2
fA fiyin ailopin
Fun Olorun Omo
pT’o feje Re ra wa,
Kuro ninu egbe,
Nisiyi, O wa, O njoba
O nri eso irora Re
3
fA f’iyin ailopin
Fun Qlorun Emi,
Eni f agbara Re
SO elese d’aye;
O pari ise igbala
O si fayo Orun k’okan.
4
fA f’ola ailopin
Fun Olodumare,
’WO Ologo meta
Sugbon Qkan soso,
B’O ti ju imo wa lo ni,
ffA o ma figbagbo yin O,