Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 870

Nitoriti ko si aini fun awon ti o beru Re.

Meter: 8.7.8.7.7. & Rcl’.

Scripture: OD. 34:9

1

mpOro aye le di ‘baje

Ohun ti mo fe le bo,

crItura mbe l’odo Jesu,

Ki l’ohun ti mo tun nfe?

Ki l’ohun ti mo tun nfe?

CHORUS

mfMo ni Krist’ ko s’aini

Owo Re ntu ebun ka

Un o ma korin yin titi

Mo ni Krist’ ko s’aini mo.

2

mpBi ayo aye ba kuna,

Lati mu inu mi dun,

mfJesu ti ru ’banuje mi,

N’nu Re mo r’ohun gbogbo,

N’nu Re mo r’ohun gbogbo.

3

mfSinu ibu ibukun Re,

Jesu si ’lekun sile,

fNinu Re mo l’ohun gbogbo,

Aini ko si fun mi mo,

Aini ko si fun mi mo.