Hymn 877
Ma beru, nitori Emi wa pelu re.
Meter: S.M.
Scripture: Gen. 26:24
1
fF’eru re f’afefe;
N’ireti, ma foya;
pOlprun gbo ’mikanle re;
Y’o gbe ori re ga.
2
N’irumi at’iji,
Y’o s’ona re fefe;
Duro de igba Re; oru
Y’o pin s'ojo ayo.
3
pOkan re ha wuwo?
O re emi re bi?
fGbon gbogbo ifoya kuro,
Le gbogbo eru lo.
4
mfB’o ko tile kuro,
Sibe orun, aye
Nso p’Olorun wa lori ’te,
O njoba lododo!
5
Fi yiyan on sise
Le ase re lowo;
’Wo y’o si f’iyanu jewo
Ogbon at’ipa Re
6
Y’o han pe imo Re
Gaju ero re lo
’Gbat’ On ba yori ise na
Ti nfo o li aya;
7
crIWO r’ailera wa,
O si mo ero wa;
diGbe owo t’are mu s’oke,
M’ekun ailera le!
8
N’nu iye tab’iku,
K’a kede oto Re,
K’aso t’ife o n ’toju Re
Tit’ opin emi wa.