Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 878

Bi enikeni ba wa ninu Kristi, O di eda titun.

Meter: D.C.M.

Scripture: II Kor. 5:17

1

mfEwa ’tanna ooro kutu,

’Mole Osan gangan,

Pipon orun ni ojoro

diWon ti yara sa to!

crA nfe enu ’bode orun,

Ita wura didan

Awa nfe Orun ododo,

Ti ki wo titi lae.

2

B’ ireti giga wa l’aye

Si ntete saki to;

Abawon melomelo ni

N b’agbada Kristian je?

A fe okan ti ki d’ese

Okan ti a we mo,

Ohun lati yin Oba wa

L’osan, l’oru titi

3

Nihin ’gbagbo pe ’reti mbe

Lati to wa soke

Lohun pipe alafia.

Ju b’a ti le fe lo

Nipa ife on ’rora Re,

Nitori iku Re.

Ma je k’a subu l’ona Re

K’a so ade wa nu.