Hymn 88
Eniti o nfi onje fun eda gbogbo: nitori anu Re duro laelae.
Meter: 7.7.7.7.
Scripture: OD. 136:25.
1
fYin Olorun Oba wa,
E gbe ohun iyin ga,
Anu Re, o wa titi;
L’ododo dajudaju.
2
mfYin Enit’o da orun
Ti o nran lojojumo,
fAnu Re, o wa titi;
L’ododo dajudaju.
3
mpAti osupa l’oru,
Tio tan ’mole jeje,
fAnu Re,owa titi
L’ododo dajudaju.
4
mfYin Enit’om’ojo ro,
T’o mu irugbin dagba,
fAnu Re, o wa titi:
L’ododo dajudaju.
5
mfEnit’ o pase fun ‘le
Lati mu eso po si;
fAnu Re, o wa titi;
L’ododo dajudaju.
6
fYin fun ikore oko,
O mu ki aka wa kun,
Anu Re, o watiti,
L’ododo dajudaju.
7
mpYin f onje t’o ju yi lo,
Eri ’bukun ailopin
fAnu Re, o wa titi;
L’ododo dajudaju.
8
unOgo f Qba olore
Ki gbogbo eda gberin,
Ogo fun Baba, Omo
At’Emi: Metalokan.